Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

APÁ 2 • ÌṢE 6:8–9:43

“Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Inúnibíni Tó Lágbára Sí Ìjọ”

“Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Inúnibíni Tó Lágbára Sí Ìjọ”

ÌṢE 8:1

Ṣé ìjọ Kristẹni ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní jẹ́ kí inúnibíni tó lágbára táwọn èèyàn ṣe sí wọn mú kí wọ́n dẹwọ́ láti máa jẹ́rìí nípa Ìjọba Ọlọ́run? Rárá o. Kàkà bẹ́ẹ̀, ńṣe ni inúnibíni tó le koko yẹn mú kí iṣẹ́ ìwàásù túbọ̀ gbilẹ̀. Ohun tá a máa jíròrò nínú apá yìí nìyẹn.