Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

APÁ 3 • ÌṢE 10:1–12:25

“Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè . . . Gba Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”

“Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè . . . Gba Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”

ÌṢE 11:1

Ṣé àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù tí wọ́n jẹ́ Júù máa fẹ́ wàásù ìhìn rere fáwọn Kèfèrí aláìdádọ̀dọ́? Nínú apá yìí, a máa rí bí ẹ̀mí Jèhófà ṣe mú káwọn Kristẹni túbọ̀ máa fìfẹ́ hàn sí onírúurú èèyàn àti bó ṣe mú kí wọ́n borí ẹ̀tanú. Àá sì rí bíyẹn ṣe mú kó ṣeé ṣe fún wọn láti wàásù ìhìn rere náà fún àwọn èèyàn gbogbo orílẹ̀-èdè.