Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú

Ṣé ẹnì kan tó o fẹ́ràn kú? Ṣé o nílò ìrànlọ́wọ́ láti kojú ẹ̀dùn ọkàn rẹ?

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ọ̀rọ̀ ìtùnú látinú Bíbélì wà nínú ìwé yìí fún àwọn tí èèyàn wọn kú.

“Kò Lè Jóòótọ́!”

Ojoojúmọ́ ni nǹkan ìbànújẹ́ máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn kárí ayé.

Ó Ha Bójúmu Láti Nímọ̀lára Lọ́nà Yìí Bí?

Ṣé ó burú tí o bá ṣọ̀fọ̀ ẹnì kan tí o fẹ́ràn tó kú?

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbé Pẹ̀lú Ẹ̀dùn-Ọkàn Mi?

Ṣé ó yẹ kó o fi bí ọ̀rọ̀ ṣe rí lára rẹ̀ hàn àbí kó o bò ó mọ́ra?

Báwo Ni Àwọn Ẹlòmíràn ṢeṢèrànwọ́?

Àwọn ọ̀rẹ́ ẹni tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ lè lo ìdánúṣe láti tu ẹni tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ nínú lọ́nà tó yẹ.

Ìrètí Tí Ó Dájú fún Àwọn Òkú

Tí ẹnì kan bá kú, ó lè ṣòro láti gbà gbọ́ pé a tún lè pa dà rí ẹni náà, ká jọ sọ̀rọ̀, ká jọ rẹ́rìn-ín tàbí ká gbá ara wa mọ́ra. Àmọ́ Bíbélì sọ pé ó máa ṣeé ṣe.

O Tún Lè Wo

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Gbìyànjú Ẹ̀ Wò

Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan lè wá ọ wa láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú rẹ lọ́fẹ̀ẹ́.

ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ

Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú

Téèyàn wa bá kú, ó lè máa ṣe wá bíi pé kò sẹ́ni tó mọ bó ṣe rí lára wa. Àmọ́ Ọlọ́run mọ̀ ọ́n, ó sì fẹ́ tù wá nínú.