Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Èèpo Èyìn Ìwé

Èèpo Èyìn Ìwé

ÈÈPO Ẹ̀YÌN ÌWÉ

Ǹjẹ́ o ti ṣìnà rí, tó o wá ń wá ẹni tó máa mú ọ mọ̀nà? Jésù Kristi ni afinimọ̀nà tí Ọlọ́run yàn láti fọ̀nà han ọmọ aráyé. Òun fúnra rẹ̀ sọ̀rọ̀, ó ní: “Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn àtàtà, mo mọ àwọn àgùntàn mi, àwọn àgù[n]tàn mi sì mọ̀ mí.” (Jòhánù 10:14) Ǹjẹ́ o mọ Olùṣọ́ Àgùntàn Àtàtà náà lóòótọ́—ṣó o mọ àwọn ànímọ́ rẹ̀, ṣó o mọ iṣẹ́ tó jẹ́ àti iṣẹ́ tó ṣe, ṣó o mọ ìtara àti ìfẹ́ tó ní? Ìwé yìí á ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti túbọ̀ mọ Jésù kó o lè máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn pẹ́kípẹ́kí.