Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÌSỌ̀RÍ 1

‘Wá Wo’ Kristi

‘Wá Wo’ Kristi

Ó ti tó nǹkan bí ẹgbàá [2,000] ọdún sẹ́yìn báyìí tí Jésù ti padà sọ́run, síbẹ̀, lójúmọ́ tó mọ́ lónìí yìí, a ṣì lè ‘wá wo’ Ọmọ Ọlọ́run yìí, ká sì rí i. (Jòhánù 1:46) Àwọn Ìwé Ìhìn Rere nínú Bíbélì jẹ́ ká mọ irú ẹni tó jẹ́, wọ́n jẹ́ ká mọ ìṣesí rẹ̀ àtàwọn ọ̀nà rẹ̀ lámọ̀dunjú. Ìsọ̀rí yìí á ṣàkópọ̀ àwọn tó ta yọ lára ànímọ́ tí Jésù ní.