Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

KẸ́KỌ̀Ọ́ LÁRA ÀWỌN Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Ébẹ́lì

Ébẹ́lì

Lo eré yìí láti kẹ́kọ̀ọ́ lára Ébẹ́lì tó jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà.

Ẹ̀yin òbí, ẹ ka Jẹ́nẹ́sísì 4:2-5 àti Hébérù 11:4 pẹ̀lú àwọn ọmọ yín, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀.

Wa eré yìí jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́ sórí ìwé.

Tẹ̀ lé àbá tó wà lójú ìwé àkọ́kọ́ láti gé àwọn àwòrán tó wà níbẹ̀, kó o sì tò wọ́n sójú ìwé kejì. Bẹ́ ẹ ṣe ń ṣiṣẹ́ lórí àwòrán yìí, ẹ dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nínú fídíò náà. Tó o bá ní àwọn àwòrán míì tó o ti gé nínú àwọn eré tó ti jáde tẹ́lẹ̀, o lè tò ó pọ̀ kó o fi ṣe ìwé.