Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Ìhìn Rere”! (Orin Àpéjọ Agbègbè 2024)

“Ìhìn Rere”! (Orin Àpéjọ Agbègbè 2024)

(Lúùkù 2:10)

Wà á jáde:

  1. 1. Ìròyìn ayọ̀ ti dé.

    Ògo f’Ọlọ́run.

    A bí Olùgbàlà kan fún wa.

    Òmìnira dé.

    A ti wá nírètí!

    (ÈGBÈ)

    Ìròyìn ayọ̀!

    Wàásù rẹ̀ fáyé.

    Ẹ yin Jèhófà!

    Ó tan ìmọ́lẹ̀ òtítọ́ fún wa.

    Wàásù pé Jésù​—

    Lọ̀nà, òótọ́, ìyè.

  2. 2. Yóò mú kí àlàáfíà wà​—

    Ní gbogbo ayé​—

    Ipasẹ̀ rẹ̀ la máa fi ríyè​—

    Ìjọba Jésù​—

    Máa dúró títí láé.

    (ÈGBÈ)

    Ìròyìn ayọ̀!

    Wàásù rẹ̀ fáyé.

    Ẹ yin Jèhófà!

    Ó tan ìmọ́lẹ̀ òtítọ́ fún wa.

    Wàásù pé Jésù​—

    Lọ̀nà, òótọ́, ìyè.

    (ÈGBÈ)

    Ìròyìn ayọ̀!

    Wàásù rẹ̀ fáyé.

    Ẹ yin Jèhófà!

    Ó tan ìmọ́lẹ̀ òtítọ́ fún wa.

    Wàásù pé Jésù​—

    Lọ̀nà, òótọ́, ìyè.