“Máa Yọ̀ Nígbà Gbogbo”
Wà á Jáde:
1. Bílẹ̀ ṣe ń mọ́ nilẹ̀ ń ṣú;
Òjò ń rọ̀, oòrùn ń ràn.
Jèhófà Ọlọ́run ló dá gbogbo àwọn nǹkan yìí
Torí ó nífẹ̀ẹ́ wa, ó fẹ́ ká láyọ̀, ká gbádùn ayé.
(ÈGBÈ)
Fi ayọ̀ kọrin sí Jèhófà,
Kó o sì fayé rẹ sìn ín.
Bá a tiẹ̀ ń níṣòro, a máa láyọ̀
Tá a bá jẹ́ olóòótọ́.
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
2. Ìdílé ni gbogbo wa;
A nífẹ̀ẹ́ ara wa.
Jèhófà Ọlọ́run ló fìfẹ́ so gbogbo wa pọ̀.
Aráyé ń ta kò wá, àmọ́ kò sóhun tó lè yà wá.
(ÈGBÈ)
Fi ayọ̀ kọrin sí Jèhófà,
Kó o sì fayé rẹ sìn ín.
Bá a tiẹ̀ ń níṣòro, a máa láyọ̀
Tá a bá jẹ́ olóòótọ́.
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
(ÀSOPỌ̀)
Jésù fẹ̀mí rẹ̀ rà wá torí pó nífẹ̀ẹ́ wa.
Èyí jẹ́ ká nírètí, ó ń fún wa láyọ̀.
(ÈGBÈ)
Fi ayọ̀ kọrin sí Jèhófà,
Kó o sì fayé rẹ sìn ín.
Bá a tiẹ̀ ń níṣòro, a máa láyọ̀
Tá a bá jẹ́ olóòótọ́.
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀! Nígbà gbogbo!
Jẹ́ ká máa yọ̀!