Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwọn Ìwà àti Àṣà Tó Ti Di Bárakú

Ìwà Rẹ

Àwọn Àṣà Tó Lè Ṣe Ẹ́ Láǹfààní

Rí i dájú pé àwọn àṣà rẹ ń ṣe ẹ́ láǹfààní dípò tá á fi kó bá ẹ.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ Ìdẹwò?

Wo ohun mẹ́ta tó o lè ṣe kó o lè borí àwọn èrò tí kò tọ́.

Oògùn Olóró àti Ọtí Líle

Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Lílo Oògùn Nílòkulò?

Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́rin tó dá lórí Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro oògùn tó di bárakú fún ẹ.

Bó O Ṣe Lè Yẹra fún Ọtí Àmujù

Àbá márùn-un tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀wọ̀n ara ẹ nídìí ọtí kódà tí nǹkan ò bá tiẹ̀ rọrùn fún ẹ.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ọtí?

Mọ ohun tó o lè ṣe kí ọwọ́ òfin má bàa tẹ̀ ẹ́, kí orúkọ ẹ má bà jẹ́ tàbí kí wọ́n má bàa fipá bá ẹ lò pọ̀, kí ọtí má sì di bárakú fún ẹ tàbí kó o fẹ̀mí ara ẹ ṣòfò.

Tí Ẹnì Kan Nínú Ìdílé Bá Ń Mutí Lámujù

Kí lo lè ṣe tí ọtí bá fẹ́ da ìdílé yín rú?

Ojú Wo ni Ọlọ́run fi Ń Wo Sìgá Mímu?

Báwo la ṣe máa mọ̀ nígbà tí Bíbélì ò dárúkọ sìgá?

Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Kí Èèyàn Mu Sìgá tàbí Igbó?

Tó bá jẹ́ pé Bíbélì ò sọ̀rọ̀ nípa sìgá mímu, báwo la ṣe lè dáhùn ìbéèrè yìí?

Ọ̀rọ̀ Ara Mi Sú Mi

Ọ̀mùtí paraku ni Dmitry Korshunov, àmọ́ ó bẹ̀rẹ̀ sí í ka Bíbélì déédéé. Kí ló mú kó yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà?

Àwọn Ẹ̀rọ Ìgbàlódé

Bó O Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Ẹ Lọ́wọ́ Àwọn Ìsọfúnni Tí Kì Í Ṣòótọ́

Ìròyìn tó ń ṣi ni lọ́nà, ìròyìn èké àti àhesọ ọ̀rọ̀ pọ̀ káàkiri, wọ́n sì lè ṣàkóbá fúnni.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Àwọn Géèmù orí Kọ̀ǹpútà?

O lè má tíì ronú nípa àǹfààní tó lè ṣe ẹ́ àti àkóbá tó lè ṣe fún ẹ.

Ṣé Fóònù Tàbí Tablet Ò Tíì Di Bárakú fún Ẹ?

Ayé ti di ayé íńtánẹ́ẹ̀tì, àmọ́ kò yẹ kó di bárakú fún ẹ. Báwo lo ṣe lè mọ̀ tí fóònù tàbí tablet bá ti di bárakú fún ẹ? Ká sọ pé ó ti di bárakú fún ẹ, kí lo lè ṣe sí i?

Tẹ́tẹ́

Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Tẹ́tẹ́ Títa?

Bíbélì ò ṣe kúlẹ̀kúlẹ̀ àlàyé nípa tẹ́tẹ́ títa, báwo la ṣe wá lè mọ irú ojú tí Ọlọ́run fi ń wò ó?

Àwọn Ohun Tó Mú Ọkàn Fà sí Ìṣekúṣe

Àwòrán Oníhòòhò​—Ó Léwu Àbí Kò Léwu?

Ọṣẹ́ wo ni àwòrán oníhòòhò ń ṣe fún ẹni tó ń wò ó àti fún ìdílé?

Ṣé Bíbélì dẹ́bi fún wíwo ohun tó ń mú ọkàn fà sí ìṣekúṣe?

Tó o bá fẹ́ mú inú Ọlọ́run dùn, ṣàyẹ̀wo ojú tí Ọlọ́run fi ń wò ohun tó ń mú ọkàn fà sí ìṣekúṣe?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Yẹra fún Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe?

Kí ló jọra nínú wíwo àwòrán ìṣekúṣe àti mímu sìgá?

Ṣé Wíwo Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Èèyàn Fà sí Ìṣekúṣe Ti Mọ́ Ẹ Lára?

Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀ pé ohun tó ń mú ọkàn èèyàn fà sí ìṣekúṣe kò dára.

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Àwòrán Oníhòòhò àti Fífi Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Fà Sí Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì?

Àwọn eré ìnàjú tó n gbé ìbálòpọ̀ lárugẹ tí wọ́pọ̀ gan-an báyìí. Ṣé ó yẹ ká máa lọ́wọ́ nínú rẹ̀ torí pé gbogbo èèyàn ló mọ̀ nípa rẹ̀?