Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Bíbélì
Ṣé ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì bá Bíbélì mu? Tí Bíbélì bá sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì, ṣé ohun tó sọ máa ń jóòótọ́? Wo àwọn ohun tó wà nínú ayé, kó o tún wo ohun táwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì tó kẹ́kọ̀ọ́ nípa wọn sọ.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Wàrà Ọmú Ìyá—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
Báwo ni wàrà ọmú ìyá ṣe ń yí pa dà kó lè bá ohun tí ọmọ nílò mu?
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Wàrà Ọmú Ìyá—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
Báwo ni wàrà ọmú ìyá ṣe ń yí pa dà kó lè bá ohun tí ọmọ nílò mu?
Èrò Àwọn Èèyàn Nípa Ìṣẹ̀dá
Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n àti Ìṣẹ̀dá
Bí Bíbélì Ṣe Bá Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Mu
Ìtẹ̀jáde
Àwọn Ìṣẹ̀dá Ọlọ́run Ń Fi Ògo Rẹ̀ Hàn
Tá a bá ronú jinlẹ̀ lórí àwọn ìṣẹ̀dá tó wà ní àyíká wa, a máa rí àwọn ànímọ́ Ẹlẹ́dàá wa, àá sì lè túbọ̀ sún mọ́ ọn.