Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n àti Ìṣẹ̀dá
Báwo Ni Ìwàláàyè Ṣe Bẹ̀rẹ̀?
Òótó ibẹ̀ ni pé ọ̀pọ̀ àwọn tó kàwé, títí kan àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ni ò fara mọ́ ọn pé òótọ́ ni ẹ̀kọ́ ẹfolúṣọ̀n.
Kí Ni Bíbélì Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Ẹlẹ́dàá?
Ṣe ohun tí Bíbélì sọ àti ohun táwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì sọ bára mu?
Ṣé Ẹfolúṣọ̀n Ni Ọlọ́run Lò Láti Dá Àwọn Nǹkan?
Kò si ibì kankan tí Bíbélì ti tako àwọn ìwádìí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́ǹsì pé àwọn ìyàtọ̀ máa ń wà nínú onírúurú ìṣẹ̀dá.
Àwọn Ọ̀dọ́ Sọ Pé Ọlọ́run Wà Lóòótọ́
Àwọn ọ̀dọ́ kan sọ ohun tó jẹ́ kó dá wọn lójú pé Ẹlẹ́dàá kan wà lóòótọ́ nínu fídíò oníṣẹ̀ẹ́jú mẹ́ta yìí.
Àwọn Ìṣẹ̀dá Ọlọ́run Ń Fi Ògo Rẹ̀ Hàn
Ṣó o máa ń kíyèsí àwọn nǹkan tí Ọlọ́run dá lójoojúmọ́? Tó o bá ń kíyè sí àwọn nǹkan yìí, wàá rí i pé ọgbọ́n Ọlọ́run ò lópin, ó sì nífẹ̀ẹ́ wa gan-an.
Kẹ́míkà Àgbàyanu Tó Ń Jẹ́ Carbon
Kò sí nǹkan mí ì tó ṣàǹfààní fún ìwàláàyè àwọn nǹkan ẹlẹ́mìí bíi carbon. Kí nìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀, kó ló sì mú kó ṣe pàtàkì?
Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?—Apá 1: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?
Ǹjẹ́ wàá fẹ́ mọ bó o ṣe lè túbọ̀ máa fi ìdánilójú ṣàlàyé ìdí tó o fi gbà gbọ́ pé Ọlọ́run wà fáwọn ẹlòmíì? Kà nípa àwọn ohun tó o lè fi fèsì tí ẹnì kan bá sọ pé ìgbàgbọ́ tó o ní pé Ọlọ́run wà kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀.
Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?—Apá 2: Ṣé Ó Yẹ Kó O Kàn Gbà Pé Òótọ́ ni Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n?
Ìdí méjì tí kò fi yẹ kó o kàn gbà pé òótọ́ ni ẹ̀kọ́ ẹfolúṣọ̀n.
Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?—Apá 3: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?
Ṣé ó yẹ kó o di alátakò ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì kó o tó lè gbà pé Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo?
Ṣó Yẹ Kí N Gba Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Gbọ́?
Èwo ló bọ́gbọ́n mu, pé gbogbo nǹkan ṣàdédé wà àbí ẹnì kan ló dá wọn?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ẹranko Ńlá Tí Wọ́n Ń Pè Ní Dinosaur?
Ṣé ó bá ohun tí sáyẹ́ǹsì sọ mu?