TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ? Imú Erin TẸ̀ Ẹ̣́ Imú Erin Iṣẹ́ ọ̀nà tó ń yani lẹ́nu ni imú erin jẹ́, kódà onírúurú àrà ni erin lè fi imú ẹ̀ dá. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí? Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Bíbélì O Tún Lè Wo TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ? Ahọ́n Ológbò—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí? Nǹkan bí ìdá mẹ́rin àsìkò tí ológbò kò fi sùn ló fi ń tọ́jú ara ẹ̀. Kí ló mú kó ṣeé ṣe fún un láti máa tọ́jú ara ẹ̀? ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ Ṣé Ọlọ́run Ló Dá Àgbáálá Ayé Yìí? Ìwé Jẹ́nẹ́sísì nínú Bíbélì sọ pé Ẹlẹ́dàá kán wà, àmọ́ ọ̀pọ̀ ò lóye àlàyé rẹ̀, wọ́n tiẹ̀ sọ pé ìtàn àròsọ ni. Ṣé a lè gba ohun tí Bíbélì sọ gbọ́? Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Imú Erin TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ? Imú Erin—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí? Yorùbá Imú Erin—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí? https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502200141/univ/art/502200141_univ_sqr_xl.jpg ijwwd àpilẹ̀kọ 38