Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Bí Àwọn Ẹyẹ Ṣe Ń Kọrin

Bí Àwọn Ẹyẹ Ṣe Ń Kọrin

Ẹ̀yà ara kán wà tó máa ń gbé ohùn jáde lára àwọn ẹyẹ, ara wọn nìkan lati lè rí i, ẹ̀yà yìí ló máa ń jẹ́ kí wọ́n lè kọ oríṣiríṣi orin títí kan àwọn tó díjú gan-an.