Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?

Bíbélì​—Ìwé Kan Tó Wá Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run (Apá 1)

Orí kejì ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Kọ́ nípa ìdí tí Bíbélì fi jẹ́ ẹ̀bùn tó ṣàrà ọ̀tọ̀ tó wá láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run.