Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Fi Hàn Pé Ìsìn Tòótọ́ Lo Fẹ́ Ṣe (Apá 2)

Orí kẹrìndínlógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Ṣó yẹ káwọn Kristẹni máa fipá mú káwọn míì gba ohun tí wọ́n gbà gbọ́? Báwo lo ṣe lè fọgbọ́n ṣàlàyé ohun tó o gbà gbọ́?