Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?

Ìràpadà​—Ẹ̀bùn Tó Ṣeyebíye Jù Lọ Tí Ọlọ́run Fúnni (Apá 1)

Orí karùn-ún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Ṣàyẹ̀wò ìdí tá a fi nílò ìràpadà àti àǹfààní tó máa ṣe fún àwọn olódodo.