Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ATỌ́NÀ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Ìrìbọmi Ló Máa Fìdí Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run Múlẹ̀ (Apá 2)

Orí kejìdínlógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Wo ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ohun tí Kristẹni kan gbọ́dọ̀ ṣe kó tó ṣèrìbọmi.