Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Gbé Ìgbé Ayé Tó Múnú Ọlọ́run Dùn (Apá 1)

Orí kejìlá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Ṣé ó ṣeé ṣe lóòótọ́ pé kí àwọn èèyàn di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run? Wo ohun tó ń gbéni ró tí Bíbélì sọ.