Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?

Kí Ni Òtítọ́ Nípa Irú Ẹni Tí Ọlọ́run Jẹ́? (Apá 1)

Orí kìíní ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Kọ́ nípa bí àwọn ohun búburú tó ń ṣẹlẹ̀ sí wa ṣe rí lára Ọlọ́run.