Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?

Ta Ni Jésù Kristi? (Apá 2)

Orí kẹrin ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Ṣàyẹ̀wò àwọn ìdí tó bá Ìwé Mímọ́ mu tó jẹ́ ká gbà gbọ́ pé Jésù kò bá Ọlọ́run dọ́gba.