Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?

Ta Ni Jésù Kristi? (Apá 3)

Orí kẹrin ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Ṣàyẹ̀wò díẹ̀ lára ànímọ́ tí Jésù fi hàn nígbà tó wà láyé àti ohun tí èyí fi hàn nípa irú ẹni tí Baba rẹ̀ jẹ́.