Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ

Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Sòótọ́

Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Sòótọ́

Téèyàn bá ti bẹ̀rẹ̀ sí í parọ́, ó máa ń ṣòro láti jáwọ́. Wàá rí ohun tó máa ń gbẹ̀yìn ẹ̀ téèyàn bá ń parọ́ àti àǹfààní téèyàn máa rí tó bá ń sòótọ́.