ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ
Sìgá Mímu Lè Ba Ayé Èèyàn Jẹ́
Ṣé ó tiẹ̀ burú téèyàn bá ń mu sìgá? Tó bá jẹ́ lóòótọ́ ló burú, báwo lo ṣe lè yẹra fún un, kó má bàa ṣàkóbá fún ẹ?