ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
Ọlọ́run Kórìíra Ìwà Ìrẹ́jẹ
Kẹ́kọ̀ọ́ látinú ìtàn Áhábù, Jẹ́síbẹ́lì, Nábótì àti Èlíjà. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!