ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
Ọlọ́run Gbà Wọ́n Kúrò Nínú Ìléru Oníná!
Kẹ́kọ̀ọ́ látinú ìtàn Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!