Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ABALA ÀWỌN Ọ̀DỌ́

Ọlọ́run Kì Í Ṣe Ojúsàájú

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa Pétérù àti Kọ̀nílíù, kí o lè mọ ohun tí ìtàn wọn kọ́ wa nípa Jèhófà Ọlọ́run. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!