IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ Kí Lo Máa Ṣe tí Ọ̀rọ̀ Ọtí Bá Délẹ̀? TẸ̀ Ẹ̣́ Ìwé yìí máa jẹ́ kó o ronú ohun tó o lè ṣe táwọn míì bá fẹ́ kó o mutí. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ ìwé àjákọ Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ọtí? Mọ ohun tó o lè ṣe kí ọwọ́ òfin má bàa tẹ̀ ẹ́, kí orúkọ ẹ má bà jẹ́ tàbí kí wọ́n má bàa fipá bá ẹ lò pọ̀, kí ọtí má sì di bárakú fún ẹ tàbí kó o fẹ̀mí ara ẹ ṣòfò. ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Ma Ṣe Jẹ́ Kí Ọtí Di Ìdẹkùn fún Ẹ Tí ọ̀pọ̀ èèyàn bá ti mutí yó, wọ́n máa ń sọ̀rọ̀ tàbí kí wọ́n hùwà tí wọ́n máa pa dà kábàámọ̀. Kí lo lè ṣe kí ọtí àmujù má bàa ṣàkóbá fún ẹ? OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọtí? Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Kí Èèyàn Máa Mu Ọtí? Bíbélì sọ ohun tó dára nípa wáìnì àti ọtí. ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ Bó O Ṣe Lè Yẹra fún Ọtí Àmujù Àbá márùn-un tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀wọ̀n ara ẹ nídìí ọtí kódà tí nǹkan ò bá tiẹ̀ rọrùn fún ẹ. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Kí Lo Máa Ṣe tí Ọ̀rọ̀ Ọtí Bá Délẹ̀? ÌWÉ ÀJÁKỌ FÚN ÀWỌN Ọ̀DỌ́ Kí Lo Máa Ṣe tí Ọ̀rọ̀ Ọtí Bá Délẹ̀? Yorùbá Kí Lo Máa Ṣe tí Ọ̀rọ̀ Ọtí Bá Délẹ̀? https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502016250/univ/art/502016250_univ_sqr_xl.jpg