IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ Pinnu Ẹni Tí Wàá Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe TẸ̀ Ẹ̣́ Ìwé yìí máa jẹ́ kó o mọ ẹni tí wàá fi ṣe àwòkọ́ṣe. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ ìwé àjákọ Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Rẹ́ni Tó Dáa Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe? Tó o bá rí ẹni tó dáa tó o lè tẹ̀lé àpẹẹrẹ rẹ̀, ìyẹn máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti yẹra fún ìṣòro, ọwọ́ rẹ máa tẹ àwọn àfojúsùn rẹ, wà á sì ṣe àṣeyọrí. Àmọ́ àpẹẹrẹ tani kó o tẹ̀lé? ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Ṣó Yẹ Kí N Mú Àwọn Míì Lọ́rẹ̀ẹ́ Yàtọ̀ Sáwọn Tá A Ti Jọ Ń Ṣọ̀rẹ́? Tó o bá wà láàárín àwọn pàtó kan tẹ́ ẹ ti jọ ń ṣọ̀rẹ́, ó lè mára tù ẹ́, àmọ́ kì í fìgbà gbogbo ṣàǹfààní. Kí nìdí? ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí O Máa Ṣe Bí Àwọn Tí Ò Ń Wò Nínú Fíìmù Tàbí Lórí Tẹlifíṣọ̀n?—Apá 1: Fún Àwọn Ọ̀dọ́bìnrin Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ tó ń ṣe bí àwọn èèyàn tó wà nínú fíìmù tàbí lórí tẹlifíṣọ̀n rò pé àwọn ń ṣe ohun tó dáa, wọn ò mọ̀ pé ìwà oníwà làwọn ń kọ́. ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí O Máa Ṣe Bí Àwọn Tí Ò Ń Wò Nínú Fíìmù Tàbí Lórí Tẹlifíṣọ̀n?—Apá 2: Fún Àwọn Ọkùnrin Sé àwọn èèyàn á gba tìẹ tó o bá ń ṣe bíi ti àwọn tí ò ń rí nínú fíìmù tàbí nínú ìpolówó? OHUN TÁWỌN OJÚGBÀ RẸ SỌ Cameron Gbé Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ Ṣé o fẹ́ káyé ẹ nítumọ̀? Gbọ́ bí Cameron ṣe ń sọ bí ayọ̀ rẹ̀ ṣe pọ̀ tó ní ibi tí kò lérò. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Pinnu Ẹni Tí Wàá Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe ÌWÉ ÀJÁKỌ FÚN ÀWỌN Ọ̀DỌ́ Pinnu Ẹni Tí Wàá Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe Yorùbá Pinnu Ẹni Tí Wàá Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502017187/univ/art/502017187_univ_sqr_xl.jpg