Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fóònù TẸ̀ Ẹ̣́ Fóònù Àwọn ọ̀dọ́ mẹ́ta sọ̀rọ̀ nípa àwọn ọ̀nà tó dáa àtèyí tí kò dáa téèyàn lè gbà lo fóònù. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù? Ọ̀rọ tó o fi ránṣẹ́ lórí fóònù lè ba àjọṣe tó o ní pẹ̀lú àwọn míì jẹ́, ó sì lè bà ẹ́ lórúkọ̀ jẹ́. Kà bó ṣe lè ṣẹlẹ̀. ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Ṣé Fóònù Tàbí Tablet Ò Tíì Di Bárakú fún Ẹ? Ayé ti di ayé íńtánẹ́ẹ̀tì, àmọ́ kò yẹ kó di bárakú fún ẹ. Báwo lo ṣe lè mọ̀ tí fóònù tàbí tablet bá ti di bárakú fún ẹ? Ká sọ pé ó ti di bárakú fún ẹ, kí lo lè ṣe sí i? ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Àkóbá Wo Ni Ìkànnì Àjọlò Lè Ṣe fún Mi? Lílo ìkànnì àjọlò lè di bárakú. Àwọn àbá yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó má bàa kó bá ẹ. ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò Máa ṣọ́ra fún ewu lórí ìkànnì tó o bá ń bá àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ṣeré níbẹ̀. ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Ṣó Di Dandan Kéèyàn Púpọ̀ Mọ̀ Mí Lórí Ìkànnì Àjọlò? Àwọn kan máa ń fẹ̀mí ara wọn wewu torí kí wọ́n lè lọ́rẹ̀ẹ́ tó pọ̀. Ṣó yẹ kéèyàn fẹ̀mí ara ẹ̀ wewu torí káwọn èèyàn lè gba tiẹ̀? Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Fóònù OHUN TÁWỌN OJÚGBÀ RẸ SỌ Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fóònù Yorùbá Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fóònù https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502013198/univ/art/502013198_univ_sqr_xl.jpg