Ìwé Tó Ṣàlàyé Àwọn Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì
Ìwé Insight on the Scriptures ṣàlàyé àwọn ọ̀rọ̀ inú Bíbélì, á sì jẹ́ kó o túbọ̀ lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. Ìwé yìí wúlò gan-an téèyàn bá fẹ́ ṣèwádìí nípa onírúurú nǹkan tí Bíbélì mẹ́nu kàn, irú bíi:
àwọn èèyàn
àwọn ìlú
igi ati ewéko
àwọn ẹranko
àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì
àwọn ọ̀rọ̀ Bíbélì
ìwà àti ànímọ́ ẹ̀dá
àwọn ọ̀rọ̀ Hébérù, Gírí ìkì àtàwọn èdé míì tí wọ́n fi kọ Bíbélì
ìwé kọ̀ọ̀kan nínú Bíbélì
Wàá rí ìwé yìí lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower, o sì lè wa ẹ̀dà PDF apá méjèèjì jáde.