Ọlọ́run Ń Mú Kó Dàgbà
Ṣé o mọ bí òtítọ́ ṣe ń dàgbà nínú ọkàn àwọn èèyàn?
Ẹ̀yin òbí, ẹ ka 1 Kọ́ríńtì 3:6, 7, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ yín.
Wa eré yìí jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́ sórí ìwé.
Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá wo fídíò Ọlọ́run Ń Mú Kó Dàgbà, ran ọmọ ẹ lọ́wọ́ láti kun àwọn àwòrán tó bá nọ́ńbà kọ̀ọ̀kan mu. Bẹ́ ẹ ṣe jọ ń ṣe é, ẹ jọ máa sọ̀rọ̀ nípa ìdáhùn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀.
O Tún Lè Wo
OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré
Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.