Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Bó O Ṣe Lè Fara Dà Á Tí Èèyàn Ẹ Bá Kú

Bó O Ṣe Lè Fara Dà Á Tí Èèyàn Ẹ Bá Kú

Tí ẹnì kan tá a fẹ́ràn bá kú, inú wa kì í dùn rárá. Àmọ́ Jèhófà máa ń ràn wá lọ́wọ́. Jẹ́ ká wo bó ṣe máa ń ṣe é.

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Bó O Ṣe Lè Fara Dà Á Tí Èèyàn Rẹ Bá Kú

Tí èèyàn wa kan bá kú, kí ló lè ràn wá lọ́wọ́ láti fara dà á?

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.