Ṣe Mọ́tò Kọ́lá
Wa eré yìí jáde. Ṣe irú mọ́tò Kọ́lá, kó o sì fún ẹnì kan.
O Tún Lè Wo
DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Jẹ́ Onínúure àti Ọ̀làwọ́
Wo bí Kọ́lá àti Tósìn ṣe túbọ̀ gbádùn ara wọn nígbà tí wọ́n jọ lo nǹkan ìṣeré wọn.
OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré
Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.