Ẹ̀kọ́ 15: Máa Fetí Sílẹ̀ Nípàdé
Kí nìdí tó fi yẹ ká máa fetí sílẹ̀ ní àwọn ìpàdé wa?
O Tún Lè Wo
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Máa Fetí Sílẹ̀ Nípàdé?
Tọ́ka sí ẹsẹ Bíbélì tó bá àwòrán kọ̀ọ̀kan mu. Báwo lo ṣe lè ṣe bí Jésù nígbà tó o bá ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa Ọlọ́run?
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.