Ẹ̀kọ́ 2: Máa Ṣègbọràn sí Jèhófà
Ṣé bèbí tó bá ṣáà ti wù wá la lè fi ṣeré? Wo bí Kọ́lá ṣe dáhùn ìbéèrè náà tó sì di ọ̀rẹ́ Jèhófà.
O Tún Lè Wo
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.