Ẹ̀kọ́ 27: Wo Ara Rẹ Bíi Pé O Wà ní Párádísè
Kí lo máa ń fọkàn yàwòrán pé ò ń ṣe nínú Párádísè?
O Tún Lè Wo
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.