Orin 2—Jèhófà Ni Orúkọ Rẹ
Orúkọ Jèhófà nítumọ̀ gan-an. Ẹ jẹ́ ká kọ ọ́ sókè!
O Tún Lè Wo
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Kọ Orin Kan sí Jèhófà!
Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá ti ṣe ilé orí bébà yìí tán, ẹ kọ orin “Jèhófà Ni Orúkọ Rẹ”, kẹ́ ẹ sì há a sórí.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.