Orin 60—Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára
Jèhófà lè fẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀, kó sì fún ẹ lágbára.
O Tún Lè Wo
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Kọ́ Ẹ
Tó o bá jẹ́ kí Ọlọ́run máa kọ́ ẹ, ó máa fi ẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀, á sì fún ẹ lágbára.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.