Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ALÁWÒRÁN

Dáfídì Nígboyà, Bí Ò Tiẹ̀ Ní Ju Ohun Ìjà Díẹ̀

Mú káàdì tí wọ́n ya àwọn èèyàn sí tó bára mu pẹ̀lú èyí tí wọ́n ya àwọn nǹkan míì sí, èyí tó dá lórí ìtàn Dáfídì àti Gòláyátì, kẹ́ ẹ sì jíròrò ohun tó mú kí Dáfídì nígboyà.