Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ALÁWÒRÁN

Hánà Ran Sámúẹ́lì Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà

Bá Sámúẹ́lì ṣe aṣọ àwọ̀lékè kan tí kò lápá, irú èyí tí ìyá rẹ̀ máa ń ṣe fún un.