Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Ráhábù

Wa káàdì eré Bíbélì yìí jáde, kó o sì kọ́ nípa Ráhábù, ẹni tó lo ìgboyà láti fi àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì méjì tí wọ́n jẹ́ amí pa mọ́. Tẹ̀ ẹ́, gé e, ká a sí méjì, kó o sì tọ́jú rẹ̀.