Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Sọ́ọ̀lù Ọba

Wa káàdì eré Bíbélì yìí jáde, kó o sì kọ́ nípa Sọ́ọ̀lù, ẹni tó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ nígbà tó kọ́kọ́ di ọba, àmọ́ tó di agbéraga nígbà tó yá. Tẹ̀ ẹ́, gé e, ká a sí méjì, kó o sì tọ́jú rẹ̀.