A Fẹ́ Kó O Wá: Àpéjọ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti 2024, ‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’
Tá a bá gbọ́ àwọn ìròyìn tí kò dáa, ó lè mú káyé sú ni kó sì dà bíi pé kò sírètí. Àmọ́, ìròyìn rere máa ń mú ká nírètí pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa!