Ìbẹ̀wò sí Bẹ́tẹ́lì
A rọ̀ ẹ́ pé kó o wá ṣèbẹ̀wò sí àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa. Bẹ́tẹ́lì la sábà máa ń pe àwọn ibí yìí. Àwọn kan lára àwọn ọ́fíìsì yìí ní àwọn àtẹ téèyàn lè wò fúnra ẹ̀.
A Lè Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣèbẹ̀wò Pa Dà: Ní ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè, àti June 1, 2023 làwọn èèyàn ti láǹfààní láti ṣèbẹ̀wò sí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni sí i, kàn sí ẹ̀ka ọ́fíìsì tí wàá fẹ́ ṣèbẹ̀wò sí. Jọ̀wọ́, má ṣe wá fún ìbẹ̀wò tí àyẹ̀wò bá fi hàn pé ó ní àrùn Kòrónà, tàbí tó ń ṣe ẹ́ bí òtútù tàbí ibà, tàbí tó o wà pẹ̀lú ẹnì kan tí àyẹ̀wò fi hàn pé ó ní àrùn náà.
Greece
Watch Tower Bible and Tract Society
Kifisias 77
GR 151 24 MAROUSI
GREECE
+30 210-619-7630
Mọ Bó O Ṣe Lè Débẹ̀
Wíwo Ọgbà Wa Yíká
Monday sí Friday
10:00 àárọ̀, 11:30 àárọ̀, àti 2:30 ọ̀sán.
Ó máa gba wákàtí 1
Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀
À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Greek, Greek Romany àti Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Greek. À ń bójú tó iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Greece àti Cyprus.