Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Barbados

Ìsọfúnni Ṣókí—Barbados

  • 288,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,350—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 30—Iye àwọn ìjọ
  • 126—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Ìfẹ́ Sún Wọn Ṣiṣẹ́​—Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù Tó Wáyé Láwọn Erékùṣù Caribbean

Fídíò yìí jẹ́ ká rí ìsọfúnni lọ́ọ́lọ́ọ́ nípa iṣẹ́ àṣekára táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó yọ̀ǹda ara wọn ṣe lẹ́yìn tí ìjì líle Irma àti Maria jà.

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Túbọ̀ Ń Ṣètò Ìrànwọ́ Lẹ́yìn Ìjì Líle Tó Jà

Àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sọ̀rọ̀ nípa ìrànwọ́ tí wọ́n ń ṣe fáwọn tí ìjì líle Hurricane Irma àti Hurricane Maria ṣèpalára fún àti bí wọ́n ṣe ń fi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tù wọ́n nínú.