Ìsọfúnni Ṣókí—Botswana
- 2,346,000—Iye àwọn èèyàn
- 2,391—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 42—Iye àwọn ìjọ
- 1,016—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Wọ́n Pàtẹ Ìṣúra Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ ní Botswana
Fídíò bèbí tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà gbàfiyèsí àwọn ọmọdé. Ọ̀wọ́ àwọn fídíò yìí máa ń jẹ́ kéèyàn rí béèyàn ṣe lè máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Bíbélì.