Ìsọfúnni Ṣókí—Finland
- 5,564,000—Iye àwọn èèyàn
- 18,186—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 272—Iye àwọn ìjọ
- 307—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Àkànṣe Ìwàásù Yọrí sí Rere ní Lapland
Kà nípa bí àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Lapland ṣe tẹ́wọ́ gba ohun táwọn Ẹlẹ́rìí sapá lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ láti ṣe kí wọ́n lè ràn wọ́n lọ́wọ́.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
A Fi Àádọ́ta Ọdún Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Ní Ilẹ̀ Olótùútù
Ka ìtan ìgbésí ayé Aili àti Annikki Mattila tí wọ́n kọ́ láti gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà nígbà tí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ aṣáájù-ọ̀nà ní àríwá Finland.