Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Taiwan

  • Taichung, Taiwan​—Wọ́n ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú tó dá lórí Bíbélì lọ ẹnì kan tó wá rajà ní ọjà Yizhong Night Market

Ìsọfúnni Ṣókí—Taiwan

  • 23,375,000—Iye àwọn èèyàn
  • 11,460—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 177—Iye àwọn ìjọ
  • 2,060—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

A Pinnu Pé A Ò Ní Kọ Iṣẹ́ Tí Jèhófà Bá Fún Wa

ÌRÒYÌN

Ètò Iṣẹ́ Àṣesìnlú Yọrí sí Rere Lórílẹ̀-èdè Taiwan

Ìjọba orílẹ̀-èdè Taiwan ṣètò pé káwọn tí ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun máa ṣiṣẹ́ àṣesìnlú ní àfidípò sí iṣẹ́ ológun.