Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Samoa

  • Apia, Samoa​—Ẹlẹ́rìí kan ń fi fídíò han ọkùnrin kan lédè Samoan

Ìsọfúnni Ṣókí—Samoa

  • 206,000—Iye àwọn èèyàn
  • 552—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 12—Iye àwọn ìjọ
  • 392—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

A Rí “Péálì Kan Tó Níye Lórí Gan-An”

Kà nípa ohun tó mú kí Winston àti Pamela Payne láti Ọsirélíà gbádùn ìgbésí ayé wọn.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

“Kí Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Erékùṣù Máa Yọ̀”

Ka ìtàn ìgbésí ayé Geoffrey Jackson tó jẹ́ ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí.