Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìlú Warwick Gbàlejò

Ìlú Warwick Gbàlejò

Àwọn aláṣẹ ìlú Warwick àtàwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ míì sọ bó ṣe rí lára wọn láti bá àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣiṣẹ́ ní oríléeṣẹ́ wa tuntun tá à ń kọ́.